Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 4:46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni Jésù tún wá sí Kánà ti Gálílì, níbi tí ó gbé sọ omi di wáìnì. Ọkùnrin ọlọ́lá kan sì wá, ẹni tí ara ọmọ rẹ̀ kò dá ní Kápérnámù.

Ka pipe ipin Jòhánù 4

Wo Jòhánù 4:46 ni o tọ