Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Afẹ́fẹ́ ń fẹ́ sí bi tí ó gbé wù ú, ìwọ sì ń gbọ́ ìró rẹ̀, ṣùgbọ́n ìwọ kò mọ ibi tí ó gbé ti wá, àti ibi tí ó gbé ń lọ: gẹ́gẹ́ bẹ́ẹ̀ ni olúkúlùkù ẹni tí a bí nípa ti Ẹ̀mí.”

Ka pipe ipin Jòhánù 3

Wo Jòhánù 3:8 ni o tọ