Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 3:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun náà ní ó tọ Jésù wá ní òru, ó sì wí fún un pé, Rábì, àwa mọ̀ pé olùkọ́ni láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá ni ìwọ ń ṣe: nítorí pé kò sí ẹni tí ó lè ṣe iṣẹ́ àmì wọ̀nyí tí ìwọ ń ṣe, bí kò se pé Ọlọ́run wà pẹ̀lú rẹ̀.

Ka pipe ipin Jòhánù 3

Wo Jòhánù 3:2 ni o tọ