Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 3:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ìdájọ́ náà pé, ìmọ́lẹ̀ wá sí ayé, àwọn ènìyàn sì fẹ́ òkùnkùn ju ìmọ́lẹ̀ lọ, nítorí tí iṣẹ́ wọn burú.

Ka pipe ipin Jòhánù 3

Wo Jòhánù 3:19 ni o tọ