Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 3:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí Ọlọ́run fẹ́ aráyé tó bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́, tí ó fi ọmọ bíbí rẹ̀ kan ṣoṣo fúnni, kí ẹnikẹ́ni tí ó bá gbà á gbọ́, má bà á ṣègbé, ṣùgbọ́n kí ó lè ní iyè àìnípẹ̀kun.

Ka pipe ipin Jòhánù 3

Wo Jòhánù 3:16 ni o tọ