Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 21:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù wí fún wọn pé, “Ẹ wá jẹun òwúrọ̀.” Kò sì sí ẹnìkan nínú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn tí ó jẹ́ bí i pé, “Ta ni ìwọ jẹ́?” Nítorí tí wọ́n mọ̀ pé Olúwa ni.

Ka pipe ipin Jòhánù 21

Wo Jòhánù 21:12 ni o tọ