Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 2:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìkòkò òkúta omi mẹ́fà ni a sì gbé kalẹ̀ níbẹ̀, irú èyí tí àwọn Júù máa ń fi ṣe ìwẹ̀nù, èyí tí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn gbà tó ìwọ̀n ogún sí ogójì gálọ́ọ̀nù.

Ka pipe ipin Jòhánù 2

Wo Jòhánù 2:6 ni o tọ