Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 2:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì fi okùn tẹ́ẹ́rẹ́ ṣe pàṣán, ó sì lé gbogbo wọn jáde kúrò nínú tẹ́ḿpílì, àti àgùntàn àti màlúù; ó sì da owó àwọn onípàṣípàrọ̀ owó nù, ó sì bi tábìlì wọn ṣubú.

Ka pipe ipin Jòhánù 2

Wo Jòhánù 2:15 ni o tọ