Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 19:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun èlò kan tí ó kún fún ọtí kíkan wà níbẹ̀, wọ́n tẹ kànrìnkàn bọ inú rẹ̀, wọ́n sì fi lé ori igi híssópù, wọ́n sì nà án sí i lẹ́nu.

Ka pipe ipin Jòhánù 19

Wo Jòhánù 19:29 ni o tọ