Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 18:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pílátù wí fún un pé, “Kín ni òtítọ́?” Nígbà tí ó sì ti wí èyí tan, ó tún jáde tọ àwọn Júù lọ, ó sì wí fún wọn pé, “Èmi kò rí ẹ̀ṣẹ̀ kan lọ́wọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Jòhánù 18

Wo Jòhánù 18:38 ni o tọ