Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 17:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsìn yìí, wọ́n mọ̀ pé ohunkóhun gbogbo tí ìwọ ti fi fún mi, láti ọ̀dọ̀ rẹ wá ni.

Ka pipe ipin Jòhánù 17

Wo Jòhánù 17:7 ni o tọ