Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 17:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kò sì sí ní ayé mọ́, àwọn wọ̀nyí sì ń bẹ ní ayé, èmi sì ń bọ̀ wá sọ́dọ̀ rẹ. Baba mímọ́, pa àwọn tí o ti fifún mi mọ́, ní orúkọ rẹ, kí wọn kí ó lè jẹ́ ọ̀kan, àní gẹ́gẹ́ bí àwa.

Ka pipe ipin Jòhánù 17

Wo Jòhánù 17:11 ni o tọ