Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 16:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ní ijọ́ náà ẹ̀yin kì ó bi mí lérè ohunkóhun. Lóòótọ́, lóòótọ́ ni mo wí fún yín, ohunkóhun tí ẹ̀yin bá bèèrè lọ́wọ́ Baba ní orúkọ mi, òhun ó fi fún yín.

Ka pipe ipin Jòhánù 16

Wo Jòhánù 16:23 ni o tọ