Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 16:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sáà ti mọ̀ pé, wọ́n ń fẹ́ láti bi òun léèrè, ó sì wí fún wọn pé, ẹ̀yin ń bi ara yín léèrè ní ti èyí tí mo wí pé, nígbà díẹ̀, ẹ̀yin kì ó sì rí mi: àti nígbà díẹ̀ ẹ̀wẹ̀, ẹ̀yin ó sì rí mi?

Ka pipe ipin Jòhánù 16

Wo Jòhánù 16:19 ni o tọ