Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 15:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbá ṣe pé èmi kò ti ṣe iṣẹ́ wọ̀n-ọn-nì láàárin wọn tí ẹlòmíràn kò ṣe rí, wọn kì bá tí ní ẹ̀ṣẹ̀: ṣùgbọ́n nísinsin yìí wọ́n sì rí, wọ́n sì kórìíra àti èmi àti Baba mi.

Ka pipe ipin Jòhánù 15

Wo Jòhánù 15:24 ni o tọ