Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 15:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbá ṣe pé èmi kò ti wá kí n sì ti bá wọn sọ̀rọ̀, wọn kì bá tí ní ẹ̀ṣẹ̀: ṣùgbọ́n nísinsin yìí wọ́n di aláìríwí fún ẹ̀ṣẹ̀ wọn.

Ka pipe ipin Jòhánù 15

Wo Jòhánù 15:22 ni o tọ