Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 15:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ rántí ọ̀rọ̀ tí mo ti sọ fún yín pé, ‘Ọmọ ọ̀dọ̀ kò tóbi ju olúwa rẹ̀ lọ.’ Bí wọ́n bá ti ṣe inúnibíni sí mi, wọ́n ó ṣe inúnibíni sí yín pẹ̀lú: bí wọ́n bá ti pa ọ̀rọ̀ mi mọ́, wọ́n ó sì pa ti yín mọ́ pẹ̀lú.

Ka pipe ipin Jòhánù 15

Wo Jòhánù 15:20 ni o tọ