Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 15:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sí ẹnìkan tí ó ní ìfẹ́ tí ó tóbi ju èyí lọ, pé ẹnìkan fi ẹ̀mí rẹ̀ lélẹ̀ nítorí àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Jòhánù 15

Wo Jòhánù 15:13 ni o tọ