Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 14:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù wí fún un pé, “Bí àkókò tí mo bá yín gbé ti tó yìí, ìwọ, kò sì tí ì mọ̀ mí síbẹ̀ fílípì? Ẹni tí ó bá ti rí mi, ó ti rí Baba: Ìwọ ha ti ṣe wí pé, ‘Fi Baba hàn wá!’

Ka pipe ipin Jòhánù 14

Wo Jòhánù 14:9 ni o tọ