Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 14:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n nítorí kí ayé lè mọ̀ pé èmi fẹ́ràn Baba; gẹ́gẹ́ bí Baba sì ti fi àṣẹ fún mi, bẹ́ẹ̀ ni èmi ń ṣe.“Ẹ dìde, ẹ jẹ́ kí a lọ kúrò níhínyìí.

Ka pipe ipin Jòhánù 14

Wo Jòhánù 14:31 ni o tọ