Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 14:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lóòótọ́ lóòótọ́ ni mo wí fún yín Ẹni tí ó bá gbà mí gbọ́, iṣẹ́ tí èmi ń ṣe ni òun yóò ṣe pẹ̀lú; iṣẹ́ tí ó tóbi ju wọ̀nyí lọ ni yóò sì ṣe; nítorí tí èmi ń lọ sọ́dọ̀ Baba.

Ka pipe ipin Jòhánù 14

Wo Jòhánù 14:12 ni o tọ