Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 12:47 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ẹnikẹ́ni bá sì gbọ́ ọ̀rọ̀ mi, tí kò sì pa wọ́n mọ́, èmi kì yóò ṣe ìdájọ́ rẹ̀ nítorí tí èmi kò wá láti ṣe ìdájọ́ ayé, bí kò ṣe láti gba ayé là.

Ka pipe ipin Jòhánù 12

Wo Jòhánù 12:47 ni o tọ