Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 10:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù dá wọn lóhùn pé, “Èmi ti wí fún yín, ẹ̀yin kò sì gbàgbọ́; iṣẹ́ tí èmi ń ṣe lórúkọ Baba mi, àwọn ni ó ń jẹ́rìí mi.

Ka pipe ipin Jòhánù 10

Wo Jòhánù 10:25 ni o tọ