Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 1:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn méjì náà sì gbọ́ ohun tí ó wí yìí, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sì í tọ Jésù lẹ́yìn.

Ka pipe ipin Jòhánù 1

Wo Jòhánù 1:37 ni o tọ