Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 1:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àṣẹ̀yìnwá àṣẹ̀yìnbọ̀ wọ́n wí fún un pé, “Ta ni ìwọ í ṣe? Fún wa ní ìdáhùn kí àwa kí ó lè mú èsì padà tọ àwọn tí ó rán wa wá lọ. Kí ni ìwọ wí nípa ti ara rẹ?”

Ka pipe ipin Jòhánù 1

Wo Jòhánù 1:22 ni o tọ