Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 1:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí sì ni ẹ̀rí Jòhánù, nígbà tí àwọn Júù rán àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì láti Jérúsálẹ́mù wá láti béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ ẹni tí òun ń ṣe.

Ka pipe ipin Jòhánù 1

Wo Jòhánù 1:19 ni o tọ