Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jákọ́bù 5:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà ará, ẹ mú sùúrù títí di ìpadàwá Olúwa. Kíyèsí i, àgbẹ̀ a máa retí èso iyebíye ti ilẹ̀, a sì mú sùúrù dè é, títí di ìgbà àkọ́rọ̀ àti àrọ̀kúrò òjò.

Ka pipe ipin Jákọ́bù 5

Wo Jákọ́bù 5:7 ni o tọ