Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jákọ́bù 4:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ẹ̀yin kò mọ ohun tí yóò hù lọ́la. Kí ni ẹ̀mí yín? Ìkuuku sáà ni yín, tí ó hàn nígbà díẹ̀, lẹ́yìn náà a sì túká lọ.

Ka pipe ipin Jákọ́bù 4

Wo Jákọ́bù 4:14 ni o tọ