Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jákọ́bù 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ẹ̀yin sì bu ọla fún ẹni tí ó wọ aṣọ dáradára tí ẹ sì wí pé, “Ìwọ jókòó níhìn-ín yìí ní ibi dáradára” tí ẹ sì wí fún talákà náà pé, “Ìwọ dúró níbẹ̀” tàbí “jókòó níhìn-ín lábẹ́ àpótí ìtìsẹ̀ mi;”

Ka pipe ipin Jákọ́bù 2

Wo Jákọ́bù 2:3 ni o tọ