Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jákọ́bù 2:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ẹnikẹ́ni lè wí pé, “Ìwọ ní ìgbàgbọ́, èmi sì ní iṣẹ́:”Fi ìgbàgbọ́ rẹ hàn mí ní àìsí iṣẹ́, èmi ó sì fi ìgbàgbọ́ mi hàn ọ́ nípa iṣẹ́ rere mi.

Ka pipe ipin Jákọ́bù 2

Wo Jákọ́bù 2:18 ni o tọ