Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jákọ́bù 2:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ẹni kan nínú yín sì wí fún pé, “máa lọ ní àlàáfíà, kí ara rẹ kí ó má ṣe tutù, kí ó sì yó,” ṣùgbọ́n ẹ kò fi nǹkan wọ̀n-ọn-nì ti ara ń fẹ́ fún wọn; èrè kí ni ó jẹ́?

Ka pipe ipin Jákọ́bù 2

Wo Jákọ́bù 2:16 ni o tọ