Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 9:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn sì ní ìgbàyà tí ó dàbí ìgbàyà irin; ìró ìyẹ́ wọn sì dàbí ìró kẹ̀kẹ́ ẹsin púpọ̀ tí ń súré lọ sí ogun.

Ka pipe ipin Ìfihàn 9

Wo Ìfihàn 9:9 ni o tọ