Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 9:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun wí fún ańgẹ́lì kẹ́fà náà tí o ni ìpè náà pé, “Tú àwọn ańgẹ́lì mẹ́rin náà sílẹ̀ tí a dè lẹ́bàá odò ńlá Yúfúrátè!”

Ka pipe ipin Ìfihàn 9

Wo Ìfihàn 9:14 ni o tọ