Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 7:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti inú ẹ̀yà Sebulúnì a fi èdìdì sàmì sí ẹgbàá mẹ́fà.Láti inú ẹ̀yà Jósẹ́fù a fi èdìdì sàmì sí ẹgbàá mẹ́fà.Láti inú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì a fi èdìdì sàmì sí ẹgbàá mẹ́fà.

Ka pipe ipin Ìfihàn 7

Wo Ìfihàn 7:8 ni o tọ