Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 7:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti inú ẹ̀yà Ásérì a fi èdídí sàmì sí ẹgbàá mẹ́fà.Láti inú ẹ̀yà Nefítalímù a fi èdìdì sàmì sí ẹgbàá mẹ́fà.Láti inú ẹ̀yà Mánásè a fi èdìdì sàmì sí ẹgbàá mẹ́fà.

Ka pipe ipin Ìfihàn 7

Wo Ìfihàn 7:6 ni o tọ