Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 6:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì wò ó, kíyèsi, ẹ̀ṣin ràndànràndàn kan: orúkọ ẹni tí ó jókòó lórí rẹ̀ ni ikú, àti ipò òkú sì tọ̀ ọ́ lẹ̀yìn. A sì fi agbára fún wọn lórí ìdá mẹ́rin ayé, láti fi idà, àti ebi, àti ikú, àti ẹranko lu orí ilẹ̀ ayé pa.

Ka pipe ipin Ìfihàn 6

Wo Ìfihàn 6:8 ni o tọ