Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 6:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ó sì di èdìdì kẹ́tà, mo gbọ́ ohùn ẹ̀dá alààyè kẹta wí pé, Wá, wò ó. Mo sì wò ó, sì kíyèsí i, ẹṣin dúdú kan; ẹni tí ó jókòó lórí ni ìwọ̀n aláwẹ́ méjì ní ọwọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ìfihàn 6

Wo Ìfihàn 6:5 ni o tọ