Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 6:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ó sì ṣí èdìdì kẹfa mo sì rí i, sì kíyèsí i, ìsẹ̀lẹ̀ ńlá kan ṣẹ̀; ọ̀run sì dúdú bí aṣọ ọ̀fọ̀ onírun, òsùpá sì dàbí ẹ̀jẹ̀;

Ka pipe ipin Ìfihàn 6

Wo Ìfihàn 6:12 ni o tọ