Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 5:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn sì ń kọ orin tuntun kan, wí pé:“Ìwọ ní o yẹ láti gba ìwé náà,àti láti ṣí èdìdì rẹ̀:nítorí tí a tí pa ọ,ìwọ sì tí fi ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ ṣe ìràpadà ènìyàn sí Ọlọ́run láti inú ẹ̀yà gbogbo,àti èdè gbogbo, àti inú ènìyàn gbogbo, àti orílẹ̀-èdè gbogbo wá:

Ka pipe ipin Ìfihàn 5

Wo Ìfihàn 5:9 ni o tọ