Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 3:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àti sí Ańgẹ́lì Ìjọ ni Filadéfíà Kọ̀wé:Ọ̀rọ̀ wọ̀nyí ni ẹni tí ó jẹ́ mímọ́ náà wí, ẹni tí ó ṣe olóòótọ́, ẹni tí ó ní kọ́kọ́rọ́ Dáfídì, ẹni tí ó sí, tí kò sí ẹni tí yóò tì; ẹni tí o sì tì, tí kò sì ẹni tí yóò ṣí i:

Ka pipe ipin Ìfihàn 3

Wo Ìfihàn 3:7 ni o tọ