Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 3:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi fún ọ ni ìmọ̀ràn pé kí o ra wúrà lọ́wọ́ mi tí a ti dà nínú iná, kí ìwọ lè di ọlọ́rọ̀; àti aṣọ funfun, kí ìwọ lè fi wọ ara rẹ̀, àti kí ìtìjú ìhòòhò rẹ̀ má ba hàn kí ìwọ sì fi ohun ìkunra kun ojú rẹ̀, kí ìwọ lè ríran.

Ka pipe ipin Ìfihàn 3

Wo Ìfihàn 3:18 ni o tọ