Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 3:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi mọ̀ iṣẹ́ rẹ, pé ìwọ kò gbóná bẹ́ẹ̀ ni ìwọ kò tútù: èmi ìbá fẹ́ pé kí ìwọ kúkú tutù, tàbí kí ìwọ kúkú gbóná.

Ka pipe ipin Ìfihàn 3

Wo Ìfihàn 3:15 ni o tọ