Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 22:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àárin ìgboro rẹ̀, àti níhà ìkínní kéjì odò náà, ni igi ìyè gbé wà, tí o máa ń so oníruurú èso méjìlá, a sì máa so èso rẹ̀ ni oṣooṣù ewé igi náà sí wà fún mímú àwọn orílẹ̀-èdè láradà.

Ka pipe ipin Ìfihàn 22

Wo Ìfihàn 22:2 ni o tọ