Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 21:26-27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

26. Wọ́n ó sì máa mú ògo àti ọlá àwọn orílẹ̀-èdè wá sínú rẹ̀.

27. Ohun aláìmọ́ kan ki yóò sì wọ inú rẹ̀ rárá, tàbí ohun tí ń ṣiṣẹ́ ìríra àti èké; bí kò ṣe àwọn tí a kọ sínú ìwé ìyè Ọ̀dọ́-Àgùntàn.

Ka pipe ipin Ìfihàn 21