Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 21:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìlú náà sì wà ní ibú mẹ́rin lọ́gbọọgba, gígùn rẹ̀ àti ìbú rẹ̀ sì dọ́gba: ó sì fi ọ̀pá-ìwọ̀n náà wọn ìlú náà wò, ó jẹ ẹgbàafà ibùsọ̀ gígùn rẹ̀ àti ìbú rẹ̀, àti gíga rẹ̀ sì dọ́gba.

Ka pipe ipin Ìfihàn 21

Wo Ìfihàn 21:16 ni o tọ