Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 20:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúkúlùkù àti mímọ́ ni ẹni tí ó ní ipa nínú àjíǹde èkíní náà: lórí àwọn wọ̀nyí ikú eekejì kò ní agbára, ṣùgbọ́n wọn ó jẹ́ àlùfáà Ọlọ́run àti ti Kírísítì, wọn ó sì máa jọba pẹ̀lú rẹ̀ ní ẹgbẹ̀rún ọdún.

Ka pipe ipin Ìfihàn 20

Wo Ìfihàn 20:6 ni o tọ