Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 2:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí ó bá ní etí kí ó gbọ́ ohun tí Ẹ̀mi ń sọ fún àwọn ìjọ. Ẹni tí ó bá ṣẹ́gun ni èmi yóò fi èso igi ìye nì fún jẹ, tí ń bẹ láàrin Párádísè Ọlọ́run.

Ka pipe ipin Ìfihàn 2

Wo Ìfihàn 2:7 ni o tọ