Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 2:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmí mọ̀ ibi tí ìwọ ń gbé, àní ibi tí ìtẹ́ Sàtánì wà. Síbẹ̀ ìwọ di orúkọ mi mú ṣinṣin. Ìwọ kò sì sẹ́ ìgbàgbọ́ nínú mi, pàápàá jùlọ ni ọjọ́ Áńtípà ẹlẹ́rì mi, olóòótọ́ ènìyàn, ẹni tí wọn pa láàrin yín, níbi tí Sàtánì ń gbé.

Ka pipe ipin Ìfihàn 2

Wo Ìfihàn 2:13 ni o tọ