Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 2:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Máṣe bẹ̀rù ohunkóhun tí ìwọ ń bọ wá jìyà rẹ̀. Kíyèsí i, èṣù yóò gbé nínú yín jù sínú túúbú, kí a lè dán yin wò; ẹ̀yin ó sì ní ìpọ́njú ní ọjọ́ mẹ́wàá: ìwọ sa se olóòtọ́ dé ojú ikú, èmi ó sì fi adé ìyè fún ọ

Ka pipe ipin Ìfihàn 2

Wo Ìfihàn 2:10 ni o tọ