Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 18:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ohùn àwọn aludùùrù, àti ti àwọn olórin,àti ti àwọn afọnrèrè, àti ti àwọn afọ̀npè,ni a kì yóò sì gbọ́ nínú rẹ mọ́ rara;àti olukulùkù oníṣọ̀nà ohunkóhun ni a kì yóò sì rí nínú rẹ mọ́ láé:Àti ìró ọlọ ní a kì yóòsì gbọ́ mọ̀ nínú rẹ láé;

Ka pipe ipin Ìfihàn 18

Wo Ìfihàn 18:22 ni o tọ